INFO:
Orisiirisii! E woran o ooo Se eyin naa ti gbo, e wo fidio yii, ibi ti won sin Seneto Isiaka Abiola Ajimobi si ni won ti so di ile igbalejo yii o, imoye...
Orisiirisii! E woran o oooSe eyin naa ti gbo, e wo fidio yii, ibi ti won sin Seneto Isiaka Abiola Ajimobi si ni won ti so di ile igbalejo yii o, imoye milionu naira ni won na sibe.Se ka waa so pe olowo se ohun gbogbo tan ni, abi ka so pe ai-mo ohun to ku lati fi owo se?Iwe iroyin Yoruba Tooto ni e ra, ogorun-un naira pere ni. | Yoruba Tooto